Iya Alariya

9ice, King Sunny Adé

Emi ni kan kan mow a
Moni baba ni gbejo
Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya laari ya ken ken eh
Iya laari ya ken ken eh eh
Iya laari ya ken ken ma jo mayo
Iya laari ya ken ken eh eh

Ti mob a lo pelu imo kan
Taabi mo re koja lo pelu inu kan
Sa dede ni blessing awa si odo mi toori mo gbagbo
Egbegberun subun lotun loosi me

Nkan kan koni se omo olorun
Okeere opoju temi
Emi nikankan mow a
Moni baba ni igbejo

Emi ni kan kan mow a
Moni baba ni gbejo
Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan
Iya laari ya ken ken eh
Iya laari ya ken ken eh eh
Iya laari ya ken ken ma jo mayo
Iya laari ya ken kеn eh eh

Ise owo mi koni di ibajе
Won tie muruwu muruw mo mi
Wan ko fe te o
Bab ti se ileri pe ma jaiye mi pe pe pe pe
Atele ese n te ono

Ajoke aiye, asake orun koni si mi lono
Eye se inu binu si mi ma
Mo ni baba ni igbejo
Emi ni kan kan mowa
Moni baba ni gbejo
Mo wowo ra mo gbagbe iyin ola ati egan

Iya laari ya ken ken eh
Iya laari ya ken ken eh eh
Iya laari ya ken ken ma jo mayo
Iya laari ya ken ken eh eh

Trivia about the song Iya Alariya by 9ice

When was the song “Iya Alariya” released by 9ice?
The song Iya Alariya was released in 2011, on the album “Versus”.
Who composed the song “Iya Alariya” by 9ice?
The song “Iya Alariya” by 9ice was composed by 9ice, King Sunny Adé.

Most popular songs of 9ice

Other artists of Worldbeat