Akoko

AMARACHUKWU KEBONKU, ASHIMI IBRAHIM

Emi ni emi l'eni na
Okunrin meta ati abo tan fi orin ko
Emi ni emi l'omo na
Okunrin merin ati abo won t'enu mo

Mo la'nu mo soro
Mo yo ake mo foh oro
Omo olooforo
Mo je akara oforo

Emi ni ah emi ni oh
Emi ma l'eni tan soh nigboro
Emi ni yaa emi ni yoo
Awon mama gan n' soro ni popo

Won lemi l'àkókó
Won lemi l'àkókó óh oh
Won lemi l'àkókó óh oh
Won lemi l'àkókó óh oh

Emi ni okunrin na
T'awon majesin nso pe m'orin gan
Emi ni emi l'omo na
Gbogbo ara adugbo lon t'enu mo

Emi baba olowo
Mo sh'owo mo j'ere
Iwa ati opolo lon lo
Awon ota ti ru po

Emi ni ah emi ni ah
Emi ma l'eni ton soh nigboro
Emi ni yaa emi ni yoo
Awon omoge n' re'di ni popo

Won l'emi l'àkókó (Iwo l'àkókó)
Won lemi l'àkókó oh oh (Iwo l'àkókó oh oh)

Trivia about the song Akoko by Brymo

When was the song “Akoko” released by Brymo?
The song Akoko was released in 2021, on the album “Ésan”.
Who composed the song “Akoko” by Brymo?
The song “Akoko” by Brymo was composed by AMARACHUKWU KEBONKU, ASHIMI IBRAHIM.

Most popular songs of Brymo

Other artists of