Okan Mi Ti Fo Wewe
Brymo
Ìyàwó kàn mí npa mi lo gere
Wọn l'olufoya ni mí oh oh
Ọkùnrin tó lè fẹ mẹta merin ah ah
Pe mo sà mo sà ẹrú dé mí mọlẹ
Ọkàn mi ti fọ' wẹwẹ
Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'lẹ'
Nígbà míràn n'ifẹ fẹ ma wù
Láti ibì ẹwà kóró ẹ'mi mi
Kò tún ní wú
Mo mọ bò ṣe burúkú
O fi lè lẹ tìpẹ'tipẹ'
Má yọ apá mí fún ọ
Òun ló n'ba ẹ' nnú jẹ
Tí 'nu mi ndún
Kò dára
Ọkàn mi ti fò wẹwẹ
Ọkàn mi ti pin yẹ'lẹ'yẹ'
Nígbà míràn, n'ifẹ fẹ má wù
Láti ibì ẹwà kọ'rọ' èmi mi
Kò tún ní wú