Aare
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si ó máa ta pàò pàò
Ọlọ'ọ'pá wá o ó máa gba rìbá
Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si ó máa ta pàò pàò
Ọlọ'ọ'pá wá o ó máa gba rìbá
Òrékelẹ'wà jẹ"a ṣeré
Eré òkúta àti gíláàsì
Mo ṣáná si ó máa ta pàò pàò
Ọlọ'ọ'pá wá o
Ẹku owurọ o
Ìròyìn láti ìgboro la mú wá kàn yín létí
Wọ'n ní ní òwúrọ' yìí àwọn ọmọ éèès!
Wọ'n ti jà wọ"gboro
Wọ'n dẹ' ti ń dáná sunlé
Wọ'n ti ń dáná sun oko
Àt'ọkọ' ayọ'kẹ'lẹ' àti èyí tí ò yọ'kẹ'lẹ'
Gbogbo ẹ' ná ń dáná sun
Ẹ gbélé yín o
Ẹ ṣọ'ra yín o
Ẹ pe àwọn ọmọ yín sọ'dọ'
Èyí tí ò bá lọ sílé ìwé, kó jókòó
Kí Ọlọ'run kí ó máa ṣọ' gbogbo wa o
Láyọ' o ẹ ṣé
Ààrẹ ń bọ' l'ájò
Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú
Èmi bàbá ọba mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k'ore
Ààrẹ ń bọ' l'ájò
Àwọn ọ'mọ'wé takùn sọ'rùn l'áàfin
Àwọn ọ'jẹ'lú dúró ṣigidi ọkọ' òfurufú
Èmi bàbá ọba mo dúró ṣigidi
Orí mi ló gbé mi k'ore