Adédọ̀tun [Album]

Olawale Olofo'ro

Awon adan n fo loke
Won fonka soju orun
Un o maa mo ibi won nlo
Eledua lo n seke won
Ko keyin si e
Ore ooo
Ohun o n wa
O wa niwaju re ooo

Adédòtun
Oyindamola mi
Ero gbogbo e ba n gberin
Adédòtun ooo

Awon adan n fo loke
Nigba igba won kun oju orun
Un o maa mo ohun wo n je
Eledua lo n so won lo n bo won
Ko pamo si e
Ore ooo
O wa lo Sokoto
O waa lapo sokoto

Adédòtun
Oyindamola mi
Ero gbogbo e ba n gberin
Adédòtun ooo
Adédòtun
O ooo oyindamola mi
Ero gbogbo e ba n gberin
Adédòtun ooo

Ko pa mo si e
Ore ooo
Ohun o n wa
Owa niwaju re ooo ooo

Trivia about the song Adédọ̀tun [Album] by Brymo

When was the song “Adédọ̀tun [Album]” released by Brymo?
The song Adédọ̀tun [Album] was released in 2020, on the album “Yellow”.
Who composed the song “Adédọ̀tun [Album]” by Brymo?
The song “Adédọ̀tun [Album]” by Brymo was composed by Olawale Olofo'ro.

Most popular songs of Brymo

Other artists of