Banuso

Abéré á lo
Abéré á lo
K’ó nà okùn ó tó dí ò
A ò ní dé bá won
A ò ní dé bá won
Ení bá ní a máà de ò

Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só
Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só

Omijé á gbe
Omijé á gbe
Ìbànújé á dèrin ò
Eniafé
Eniafé lamò o
A ò mo’ni tó fé ni ò

Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só
Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só

Ení bá ma b’ésù jeun
Síbíi rè á gùn gan
Eni ò mò wáwù
Óma tee
Òsèlú mà ló layé ò

Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só
Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só

Èyin ará
Ewá gbó òò
Òrò kan se ùrùn ùrùn nínú iii
Sé kín só
Kín só

Ká bá’núso
Bá’núso
N’òní b’enìyan só

Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só
Bá’núso
Bá’núso
Má b’enìyan só

Most popular songs of Brymo

Other artists of