Olanrewaju

Olawale Olofo'ro

Igba o lọ bi orere
Bo ba koro oṣi maa dun ah
Eni to ni suuru kii ṣeyan kekere
Bo ba kan lẹ oṣi maa goke ah
Boo ba ṣe un tọ fe won maa kẹyin si e ẹh a ẹh
Bo ba ṣe tirẹ o o ma jẹ ire fun ẹ

Ọlanrewaju ọmọ ọba
E ma suure da gba
won ni ko o ṣe were roora ṣe
E ma suure da gba oo

Olooto ko ni ku si bi ọtẹ ooo
Olanrewaju ọmọ mi
E ma suure da gba oo

Igba o lọ bi orere
Bọmọde oku oo oṣi maa da gba
Ṣọra funja ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ
Oun tio to o oṣi maa pọ da nu

Gbogbo eni abi lo ma ku ẹh a ẹh
Iwa ta a wu lo ma ku ẹh a ẹh
Ọlanrewaju ọmọ oba
E ma suure da gba o
Won ni ko ṣe were roora ṣe
E ma suure da gba oo

Olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo
Ọlanrewaju ọmọ mi
E ma suure da gba o
Olooto ko ni ku sipo ika oo
Olooto ko ni ku sibi ote oo

Ọlanrewaju ọmọ ọba
Ee ma suure dagba oo
Ọlanrewaju ọmọ mi
Ee ma suure da gba oo

Trivia about the song Olanrewaju by Brymo

When was the song “Olanrewaju” released by Brymo?
The song Olanrewaju was released in 2018, on the album “Oṣó”.
Who composed the song “Olanrewaju” by Brymo?
The song “Olanrewaju” by Brymo was composed by Olawale Olofo'ro.

Most popular songs of Brymo

Other artists of