Olúmọ
Olawale Olofo'ro
Mo n lọ sake mo fẹ' lọ rọ'jọ'gbọ'n o
Mo n lo s'Abeokuta mo fe lọ rí
Omo Soyínka aaaaa
Osoyinka ooooo
Osoyinka aaaaa
Osoyinka ooooo
Be lọ sowu
Be ba rare'mu o
Be ba ri baba Iyabo' ẹ ba mi ki
Ẹbọra owu
Ẹbọra owu ooooo
Ẹbọra owu eh
Ẹbọra owu ooooo
Be lọ s' Abeokuta ìlo Olumo
Bẹ ba ra'lake ẹ ba mi ki