Orun n Mooru

Olawale Olofo'ro

Teti ko gbo
Ile oba ti gbanna
Awon ijoye won ni kosowo lowo oba
Won soro e leyin
Olori lo n rofo l'oba n san ra

Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo

Oba o gbepo pari, ko binu
O ni kiwon pade ohun laafin
Awon ijoye won tiju bonba r'oba
Won soro e leyin
Olori lo n roka l'oba n san ra

Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo

Orun n mooru
Orun n mooru
Eni lo lomo
Eni bo lomo

Trivia about the song Orun n Mooru by Brymo

Who composed the song “Orun n Mooru” by Brymo?
The song “Orun n Mooru” by Brymo was composed by Olawale Olofo'ro.

Most popular songs of Brymo

Other artists of